Wednesday, 11 April 2012

IPETU-IJESA ANTHEM

IPETU ARO-ODO ANTHEM

 Ipetu Aro-Odo, ile ogbon
Ipetu Aro-Odo, ile imo
Ibi ori damisi maa re o
Ipetu ilu alagbara.

Chorus:  E gbe gegege e gbe laruge (2ce)
Ibi t’olu damisi maa re o
Maa gbe gegege maa gbe laruge
Ipetu Aro-Odo alagbara.

Ipetu mo seleri pe
Ohun ti mo ni maa fifun o
Ohun ti mo ni maa gbe o ga
Ile olu da mi si ni o je.

Chorus:  E gbe gegege e gbe laruge (2ce)
Ibi t’olu damisi maa re o
Maa gbe gegege maa gbe laruge
Ipetu Aro-Odo alagbara.

Gbogbo omo Ipetu e dide se
E fi ipile rere lele o
Nigba t’ojo ogbo ba de ba yin
Oruko yin koni pare.

Chorus:  E gbe gegege e gbe laruge (2ce)
Ibi t’olu damisi maa re o
Maa gbe gegege maa gbe laruge
Ipetu Aro-Odo alagbara.

Ipetu Aro-Odo yi ti gbogbo wa ni
Ko ma gbodo baje
Tori ko si b’omiran ti a le lo
Ajo ko dabi ile
E je ka sowo po ka fimo sokan
E gbe ki ngbe.
Refrain:   Gbee ki n gbee (2ce)
E je ka sowo po ka fimo sokan
gbee ki n gbee.

The Anthem was first rendered on Ipetu-Ijesa Day Nov. 2000 by Banjolat Friendship Academy Students, conducted by Staffer Abiodun Ajayi, subsequently approved by the Ajalaye of Ipetu-Ijesa.

Reference:
Banjolat Hymnal, Edited by Rotr. (Chief) ‘Banji Olatona J.P., First Edition, 2003.

N.B:
Rotr. (Chief) ‘Banji Olatona J.P. is the Founder & Proprietor of the Prestigious Banjolat International Nur./Pry School & Banjolat Friendship Academy, Ipetu-Ijesa, Osun State.

No comments:

Post a Comment